To continue using the site you need to read the revised version and agree to the policies
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti dá olùkọ́ mẹta dúró bayi látàrí ẹ̀sùn ìbánilòpọ̀ lọ́nà àìtọ́ tí wọ́n fi kàn wọn nílé ẹ̀kọ́ Basic School, to wà n'ilu Ògbómọ̀ṣọ́, nipinle Ọ̀yọ́. Àtẹ̀jáde yí wáyé latenu ẹni tí ó jẹ́ kọmíṣọ́nà fún ètò ẹ̀kọ́, ìmọ̀ Sayennsi àti ìmọ̀ ìgbàlódé, Arákùnrin Rahman ...
Pẹ̀lú pé kò tí ì ju bí i wákàtí mẹẹdọgbọn lọ tí ìṣẹ̀lẹ̀ iná ṣúyọ ni ilé ìdalẹ̀nù kan tí ìjọba ò fọwọ́ sí ní agbègbè Rumukoro ní ìjọba ìbílẹ̀ Obio/Akpor nipinle Rivers, ìṣẹ̀lẹ̀ iná kan tún ti n ṣẹlẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́ bayi ni agbègbè Nembe/Bonny/Jetty n'ilu Port Harcourt. Ìṣẹ̀lẹ̀ ìjàm...
Bí ó ti lẹ̀ jẹ́ pé arẹ́ májà kan ò sí, àmọ́ ajà má parí ni kò dáa. Èyí gan-an ló mú kí inú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn Olólùfẹ́ àwọn ònkọrin tàkasúfèé nì Paul àti Peter tí wọn jẹ́ ìbejì ọmọ ìyá kan náà tí wọn ń jẹ́ "Psquare" ó máa dùn nígbà tí Wọ́n ríwọn papọ̀ lana ọjọ́rú ọjọ́ kẹtàdínlógún o...
Afrosky, a vibrant social media platform dedicated to connecting people of African descent worldwide. We provide a space for users to share their experiences, connect with like-minded individuals, and celebrate African culture and heritage.
We strive to foster a supportive and inclusive community where users feel empowered to express themselves authentically.